IKÚ (Another "Reverence" to the Soul Reaper!)

IMG-20160617-WA0006

Iku!
Ikú d’óró; Ikú ş’èkà
Ó wò sùn sùn; ó mę ni’re lo
Àjànàkú sún bí Òkò
Alákíkanjú d’alàí mo şe.

Ikú!
No one prays for your visitation
You walk with sorrow
Do you have anything in common?
You do scare to predict tomorrow.

Ikú!
You are so disrespectful
Creature chameleons to Sand
Victim might not be useful
Breath is difficult to find.

Ikú!
Ikú d’óró; Ikú ş’èkà
Òré mi o jé fura
Ilè ńjęnìyàn
Má tęę bàşù bàşù.

Ikú!
Unpredictable fortune
Could shut sight of creature
Never planned to happen
What an August visitor!

Ikú!
Ó mú ęni bí işan orùn lo
Ó kán eyín òkáń
A so èyàn d’aláìlárá
A so omo d’aláìní baba.

Ikú!
Bó ti wà l’átètèkóşe; Ó ń bę nísinsìnyín
Bęęni yío sì ma rí
Nígbà gbogbo
Ayé àìnípękun.

Ikú!
I can’t write all about you
You possess than I can explain
You shameless Ikú!
Get out like you’ve never done.

Poet: Oyedokun Ibukun S.
08079411072
ibukunoyedokun08@gmail.com

Advertisements

Share your thoughts...

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s